29/07/2026
ASIRI TOSO IRAWO OMI METETA PAPO
Irawo omi pinsi meta
1)irawo omi agbara (cancer) 🦀
2)irawo omi tutu (Scorpio) ♏️
3)irawo omi tikiru (Pisces) 🐟
Awon oni irawo yi je alagbara, akanda eledumare, oni mimo ni niwon je,won ma nfema gbogbo nkan, olohun situn fun won ni ogbon iginle ebun ala Lila(dream) wa fun won ati emi ifura(vigilant).. irawo yi imisi olohun beni ara won, won olohun situn fun won ni isipaya okanwon man riran lati inu okan (spiritual power) ogun idile ma nba won ja gan.. ogun dudu ama sise fun awon apakan ninu irawo yi.. Besini ogun dudu ki sise fun awon miran ninu won, afi eniti oba se iwadi nipa arare latima awon nkan tole ma se ati nipa ogun tio le lo..
asasi ki tete ran won tori omo elegbe po ninu won, awon emi airi(spirits) man wa pelu won.. koda pupo ninu won man ni oko orun tabi aya orun, agaga awon omo elegbe inu won , ki omo elegbe inu irawo yi ma se sara si odo dada kio situn mabo ori re dada.. Kio maba damu pupo laiye tori isoro ama po fun awon oni irawo yi.....
Alaje omo ni won ologo eniyan niwon, eniyan tiwon wa si ile aiye lati wase omo araye ni ore niwon je, olokiki eniyan ni won olohun fun wonni imo ijinle ki won wo nkan ki won si ma ibi ti yio yori si, awon obinrin inu won ma ka ile oko tori oju won ki gbe ibi kan latara ewa ti olohun fun won ati agbara ibalopo, tori idi eyi ni pupo ninu won fi ma se sina awon apakan inu won situ ma mu oti afi eniti oba ni iberu olohun ninu won , won situn ni igberaga ni tori ebun aje ati imo ati agbara ti olohun fun won lati ode orun wa si aiye.. awon onirawo yi won gbodo je eda ti yio ma se adura dada tori adura dara funwon...
kiwon situn ma se sara fun awon egbe won ki Wonleba ma se iranlowo fun won dada , odara ki awon irawo yi ma fi omi se adura dada tori won mari gbigba adura pupo .. pupo ninu awon onirawo yi okin ni emi idarijin ti eniyan base won, agaga eniti oba gba omi je ni oju won ti won bafise epe fun oni tohun, kosi eniti ole niki nkan ti wonso yi ma se